Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 5:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà láti ìṣinṣin yìí lọ, àwa kò mọ ẹnìkan nípa ti ara mọ́; bí àwa tilẹ̀ ti mọ Kírísítì nípa ti ara, ṣùgbọ́n níṣinṣin yìí àwa kò mọ̀ ọ́n bẹ́ẹ̀ mọ́.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 5

Wo 2 Kọ́ríńtì 5:16 ni o tọ