Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sì kọ̀wé bí mo tí kọ sí yín pé, nígbà tí mo bá sì de, kí èmi má ṣe ni ìbànújẹ́ lọ́dọ̀ àwọn ti ìbá mú mi ní ayọ̀: nítorí tí mo ní ìgbẹkẹlé nínú gbogbo yín, wí pé ẹ̀yin yóò jẹ́ alábápín ayọ̀ mi.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 2

Wo 2 Kọ́ríńtì 2:3 ni o tọ