Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 11:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tàbí ẹ̀ṣẹ̀ ni mo dá bí èmi ti ń rẹ ara mí sílẹ̀ kí a lè gbé yín ga, nítorí tí mo wàásù ìyìn rere Ọlọ́run fún un yín lọ́fẹ̀ẹ́.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 11

Wo 2 Kọ́ríńtì 11:7 ni o tọ