Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 10:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí a bà à lè wàásù ìyìn rere ní àwọn ìlú tí ń bẹ níwájú yín, kí a má sì ṣògo nínú ààlà ẹlòmíràn nípa ohun tí ó wà ní àrọ́wọ́tó.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 10

Wo 2 Kọ́ríńtì 10:16 ni o tọ