Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 10:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n èmi Pọ́ọ̀lù fúnra mi fi inú tútù àti ìwà pẹ̀lẹ́ Kírísítì bẹ̀ yín, èmi ẹni ìrẹ̀lẹ̀ lójú yín nígbà tí mo wà láàárin yín, ṣùgbọ́n nígbà tí èmi kò sí, mo di ẹni ìgboyà sí yín.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 10

Wo 2 Kọ́ríńtì 10:1 ni o tọ