Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Tímótíù 6:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ìwọ ènìyàn Ọlọ́run, sá fún nǹkan wọ̀nyí; kí ó sì máa lépa òdodo, ìwà-bí-Ọlọ́run, ìgbàgbọ́, ìfẹ́ sùúrú, ìwà tútù.

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 6

Wo 1 Tímótíù 6:11 ni o tọ