Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Tímótíù 5:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ọkùnrin tàbí obìnrin kan tí ó gbàgbọ́ bá ní àwọn opó, kí ó máa ràn wọ́n lọ́wọ́, kí a má sì di ẹrù lé ìjọ, kí wọn lè máa ran àwọn ti í ṣe opó nítòótọ́ lọ́wọ́.

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 5

Wo 1 Tímótíù 5:16 ni o tọ