Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Tímótíù 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí a ti mọ̀ pé, a kò ṣe òfin fún olódodo, bí kò ṣe fún àwọn aláìwà-bí-Ọlọ́run àti àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, fún àwọn aláìmọ́ àti àwọn ẹlẹ́gàn, fún àwọn tí ń pa baba àti àwọn tí ń pa ìyá àti àwọn apànìyàn,

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 1

Wo 1 Tímótíù 1:9 ni o tọ