Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Tímótíù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ète àṣẹ náà ni ìfẹ́ ti ń jáde wá láti inú ọkàn mímọ́ àti ẹ̀rí-ọkàn rere àti ìgbàgbọ́ àìṣẹ̀tàn.

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 1

Wo 1 Tímótíù 1:5 ni o tọ