Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Tẹsalóníkà 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀rọ̀ Olúwa ti gbilẹ̀ níbi gbogbo láti ọ̀dọ̀ yín láti agbégbé Makedóníà àti Ákáyà lọ, ìgbàgbọ́ yín nínú Ọlọ́run tàn káàkiri. Nítorí náà, a kò ni láti ṣẹ̀ṣẹ̀ ń sọ fún wọn nípa rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Tẹsalóníkà 1

Wo 1 Tẹsalóníkà 1:8 ni o tọ