Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Tẹsalóníkà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pọ́ọ̀lù, Sílásì àti Tímótíù.A kọ ọ́ sí ìjọ tí ó wà ní ìlú Tẹsalóníkà, àwọn ẹni tí ó jẹ́ ti Ọlọ́run Baba àti ti Olúwa Jésù Kírísítì.Kí ìbùkún àti àlàáfíà láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba àti Jésù Kírísítì kí ó jẹ́ tiyín.

Ka pipe ipin 1 Tẹsalóníkà 1

Wo 1 Tẹsalóníkà 1:1 ni o tọ