Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Pétérù 3:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ má ṣe fi búburú san búburú, tàbí fi èébú san èébú: ṣùgbọ́n kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ máa súre; nítorí èyí ni a pè yín sí, kí ẹ̀yin lè jogun ìbùkún.

Ka pipe ipin 1 Pétérù 3

Wo 1 Pétérù 3:9 ni o tọ