Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Pétérù 3:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gẹ́gẹ́ bí Sárà ti gbọ́ ti Ábúráhámù, tí ó ń pè é ní olúwa rẹ̀. Ọmọbìnrin ẹni tí ẹ̀yin jẹ́, bí ẹ̀yin bá ń ṣe rere, tí ohunkóhun kò sí dẹ́rùbà yín.

Ka pipe ipin 1 Pétérù 3

Wo 1 Pétérù 3:6 ni o tọ