Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Pétérù 3:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àpẹẹrẹ èyí ti ń gbà yín là nísinsìnyìí pẹ̀lú, àní ìtẹ̀bọmi, kì í ṣe wíwẹ́ èérí ti ara nù, bí kò ṣe ìdáhùn ẹ̀rí ọkàn rere si Ọlọ́run, nípa àjíǹde Jésù Kírísítì.

Ka pipe ipin 1 Pétérù 3

Wo 1 Pétérù 3:21 ni o tọ