Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 9:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti borí nínú eré ìdíje, ẹ ní láti sẹ́ ara yín nínú ọ̀pọ̀ nǹkan tí ó lè fá yín sẹ́yín nínú sísa gbogbo agbára yín. Wọ́n ń ṣe èyí láti gba adé ìdíbàjẹ́. Ṣùgbọ́n àwa ń sá eré ìje tiwa láti fi gba adé ọ̀run tí kò lè bàjẹ́ láéláé.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 9

Wo 1 Kọ́ríńtì 9:25 ni o tọ