Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 9:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí mo bá wà láàrin àwọn tí kò sí lábẹ́ òfin, èmi náà yóò dàbí ẹni tí kò sí lábẹ́ òfin (èmi kì í ṣe aláìlófin sí Ọlọ́run, ṣùgbọ́n èmí ń bẹ lábẹ́ òfin Kírísítì), kí èmi le jèrè àwọn tí kò sí lábẹ́ òfin.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 9

Wo 1 Kọ́ríńtì 9:21 ni o tọ