Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 9:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìrònú àwọn ẹlòmíràn, èmi kì í ṣe àpósítélì. Dájúdájú àpósítélì ni mo jẹ́ fún un yín, tí n kì bá ṣe fún àwọn ẹlòmíràn. Nítorí èdìdì iṣẹ́ àpósítélì mi ni ẹ̀yin jẹ́ nínú Olúwa.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 9

Wo 1 Kọ́ríńtì 9:2 ni o tọ