Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 7:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nínú èrò tèmi obìnrin náà yóò ní ayọ̀ púpọ̀, tí kò bá ṣe ìgbéyàwó mìíràn mọ́. Mo sì rò pé mo ń fún un yín ní àmọ̀ràn láti ọ̀dọ̀ Ẹ̀mí Ọlọ́run nígbà tí mo ń sọ nǹkan wọ̀nyí.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 7

Wo 1 Kọ́ríńtì 7:40 ni o tọ