Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 7:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nítorí àgbérè pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ̀ kí ọkùnrin kọ̀ọ̀kan gbéyàwó tirẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni kí obìnrin kọ̀ọ̀kan ní ọkọ tirẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 7

Wo 1 Kọ́ríńtì 7:2 ni o tọ