Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 7:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báwo ni ẹ̀yin aya ṣe mọ̀ pé ẹ̀yin ni yóò gba ọkọ yín là? Bákan náà ni a lè wí nípa ọkọ tí í ṣe onígbàgbọ́ pé, kò sí ìdánilójú pé aya aláìgbàgbọ́ le yípadà láti di onígbàgbọ́ nípa dídúró ti ọkọ.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 7

Wo 1 Kọ́ríńtì 7:16 ni o tọ