Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 7:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé ó ṣe é ṣe kí a lè mú ọkọ tí kò gba Kírísítì gbọ́ súnmọ́ Ọlọ́run nípa aya tí í ṣe onígbàgbọ́, a sì le mú ìyàwó tí kò gba Kírísítì gbọ́ súnmọ́ Ọlọ́run nípa ọkọ tí í ṣe onígbàgbọ́. Bí kò bá ṣe bẹ́ẹ̀, àwọn ọmọ wọn yóò jẹ́ aláìmọ́. Ṣùgbọ́n bí wọn kò bá kọ ara wọn sílẹ̀, ó ṣe é ṣe kí àwọn ọmọ wọn di mímọ́.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 7

Wo 1 Kọ́ríńtì 7:14 ni o tọ