Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 6:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n dípò èyí, arákùnrin kan ń pe arákùnrin kejì lẹ́jọ́ sí ilé ẹjọ́ níwájú àwọn aláìgbàgbọ́.!

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 6

Wo 1 Kọ́ríńtì 6:6 ni o tọ