Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 6:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

tàbí àwọn olè, tàbí àwọn wọ̀bìà, tàbí àwọn ọ̀mútí, tàbí àwọn apẹ̀gàn, tàbí àwọn alọ́nilọ́wọ́gbà ni yóò jogún ìjọba Ọlọ́run.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 6

Wo 1 Kọ́ríńtì 6:10 ni o tọ