Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 4:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà ni mo ṣe rán Tìmótíù sí i yín, ẹni tí í ṣe ọmọ mi olùfẹ́ àti olódodo nínú Olúwa, ẹni tí yóò máa mú yín rántí ọ̀nà mi tí ó wà nínú Kírísítì, gẹ́gẹ́ bí mo ti ń kọ́ni nínú gbogbo ìjọ níbi gbogbo.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 4

Wo 1 Kọ́ríńtì 4:17 ni o tọ