Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 3:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ ẹ̀yin kì í ṣe ènìyàn lásán bí? Níwọ̀n ìgbà tí ẹ ba ń sọ pé, “Èmi ń tẹ̀lé Pọ́ọ̀lù,” àti ti ẹlòmíràn tún wí pé, “Èmi ń tẹ̀lé Àpólò.”

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 3

Wo 1 Kọ́ríńtì 3:4 ni o tọ