Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 3:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Iṣẹ́ olúkúlùkù ènìyàn yóò hàn, nítorí ọjọ́ náà yóò fi í hàn, nítorí pé nínú iná ni a ó ti fi hàn, iná náà yóò sì dán irú iṣẹ́ èyí tí olùkúlùkú ṣe wò.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 3

Wo 1 Kọ́ríńtì 3:13 ni o tọ