Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 3:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa oore-ọ̀fẹ́ tí Ọlọ́run tí fi fún mi, gẹ́gẹ́ bí ọlọ́gbọ́n ọ̀mọ̀lé, mo ti fi ìpìlẹ̀ ilé lélẹ̀, ẹlòmíràn sì ń mọ lé e, ṣùgbọ́n kí olúkúlùkù kíyèsára bí yóò ṣe mọ ọ́n lé e.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 3

Wo 1 Kọ́ríńtì 3:10 ni o tọ