Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígba tí ẹ̀mí tọ̀ yín wá, ẹ̀yin ará, kì í ṣe nípa ọ̀rọ̀ gíga àti ọgbọ́n gíga ni mo fi bá yín sọ̀rọ̀, nígbà tí èmi ń sọ̀rọ̀ ohun ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run fún un yín.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 2

Wo 1 Kọ́ríńtì 2:1 ni o tọ