Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 15:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ará, ǹjẹ́ èyí ní mo wí pé, ara àti ẹ̀jẹ̀ kò lè jogún Ìjọba Ọlọ́run, bẹ́ẹ̀ ni ìdíbàjẹ́ kò lé jogún àìdíbàjẹ́.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 15

Wo 1 Kọ́ríńtì 15:50 ni o tọ