Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 14:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ nísinsìnyìí, ará, bí mo bá wá sí àárin yín, tí mo sì ń sọ̀rọ̀ ní èdè àìmọ̀, èrè kín ni èmí óò jẹ́ fún yin, bi ko ṣe pé mo bá ń bá yín sọ̀rọ̀, yálà nípa ìṣípayá, tàbí ìmọ̀ tàbí nípá iṣọtẹ́lẹ̀, tàbí nipá ẹ̀kọ́?

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 14

Wo 1 Kọ́ríńtì 14:6 ni o tọ