Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 14:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹnikẹ́ni bá ró ará rẹ̀ pé òun jẹ́ wòlíì, tabí òun jẹ́ ẹni tí ó ní ẹ̀bùn ẹ̀mí, jẹ́ kí nǹkán wọ̀nyí ti mo kọ sí yin yé e dájú pé ofin Olúwa ni wọ́n.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 14

Wo 1 Kọ́ríńtì 14:37 ni o tọ