Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 14:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹnìkan bá fi èdè fọ̀, kí ó jẹ ènìyàn méjì, tàbi bí ó pọ̀ tán, kí ó jẹ́ mẹ́ta, kí ó sọ̀rọ̀ ní ọ̀kọ̀ọ̀kan, kí ẹnìkan sì túmọ̀ rẹ̀,

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 14

Wo 1 Kọ́ríńtì 14:27 ni o tọ