Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 14:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ kín ni èmi ó ṣe? Èmí o fí ẹ̀mí mí gbàdúrà, èmi ó sí fí ọkàn gbàdúrà pẹ̀lú: Èmi ó fi ẹ̀mí kọrin, èmi o sí fi ọkàn kọrin pẹ̀lú.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 14

Wo 1 Kọ́ríńtì 14:15 ni o tọ