Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 13:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí mo bá fi gbogbo nǹkan tí mo ní tọrẹ fún àwọn aláìní, tí mo sì fi ara mi fún ni láti sùn ṣùgbọ́n tí n kò ní ìfẹ̀, kò ní èrè kan fún mi.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 13

Wo 1 Kọ́ríńtì 13:3 ni o tọ