Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 13:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí èmi tilẹ̀ lè sọ oríṣìíríṣìí èdè tí ènìyàn àti ti ańgẹ́lì, tí n kò bá sì ní ìfẹ́, mo kàn ń pariwo bí agogo lásàn ni tàbí bí i Síḿbálì olóhùn gooro.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 13

Wo 1 Kọ́ríńtì 13:1 ni o tọ