Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 5:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa sì mọ̀ pé Ọmọ Ọlọ́run dé, ó sì tí fi òye fún wa, kí àwa lè mọ ẹni tí í ṣe òtítọ́, àwa sì ń bẹ nínú ẹni tí í ṣe òtítọ́, àní, nínú Ọmọ rẹ̀, Jésù Kírísítì. Èyí ni Ọlọ́run òtítọ́, àti ìyè àìnípẹ̀kun.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 5

Wo 1 Jòhánù 5:20 ni o tọ