Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 5:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nǹkan wọ̀nyí ni mo kọ̀wé rẹ̀ sí yín, àní sí ẹ̀yin tí ó gba orúkọ Ọmọ Ọlọ́run gbọ́; kí ẹ̀yin lè mọ̀ pé ẹ̀yin ní ìyè àìnípẹ̀kun, àní fún ẹ̀yin tí ó gba orúkọ Ọmọ Ọlọ́run gbọ́.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 5

Wo 1 Jòhánù 5:13 ni o tọ