Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 4:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbẹ̀rù kò sí nínú ìfẹ́; ṣùgbọ́n ìfẹ́ tí ó pé ń lé ìbẹ̀rù jáde; nítorí tí ìbẹ̀rù ni ìyà nínú. Ẹni tí ó bẹ̀rù kò pé nínú ìfẹ́.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 4

Wo 1 Jòhánù 4:18 ni o tọ