Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnikẹ́ni kò ri Ọlọ́run nígbà kan rí. Bí àwa bá fẹ́ràn ara wa, Ọlọ́run ń gbé inú wa, a sì mú ìfẹ́ rẹ̀ pé nínú wa.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 4

Wo 1 Jòhánù 4:12 ni o tọ