Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 3:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ó bá sì pa òfin rẹ̀ mọ́ ń gbé inú rẹ̀, àti òun nínú rẹ̀. Àti nípa èyí ni àwa mọ̀ pé ó ń gbé inú wa, nípa Ẹ̀mí tí ó fi fún wa.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 3

Wo 1 Jòhánù 3:24 ni o tọ