Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 3:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ohunkòhun tí àwa bá béèrè, ni àwa ń rí gbà lọ́dọ̀ rẹ̀, nítorí tí àwa ń pa òfin rẹ̀ mọ́, àwa sì ń ṣe àwọn nǹkàn tí ó dára lójú rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 3

Wo 1 Jòhánù 3:22 ni o tọ