Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ wo irú ìfẹ́ tí Baba fi fẹ́ wa, tí a fi ń pè wá ní Ọmọ Ọlọ́run; bẹ́ẹ̀ ni a sáà jẹ́. Nítorí èyí ni ayé kò ṣe mọ̀ wá, nítorí tí kò mọ̀ ọ́n.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 3

Wo 1 Jòhánù 3:1 ni o tọ