Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pẹ̀lúpẹ̀lú, òfin tuntun ni mo ń kọ̀wé rẹ̀ sí yín; èyí tí í ṣe òtítọ́ nínú rẹ̀ àti nínú yin, nítorí òkùnkùn ń kọjá lọ, ìmọ́lẹ́ òtítọ́ sì tí ń tàn.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 2

Wo 1 Jòhánù 2:8 ni o tọ