Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin ọmọ mi ọ̀wọ́n, mo kọ ìwé nǹkan wọ̀nyí sí yín, kí ẹ̀yin má bà á dẹ́ṣẹ̀. Ṣùgbọ́n bí ẹnikẹ́ni bá sì dẹ́ṣẹ̀, àwa ni alágbàwí lọ́dọ̀ Baba: Jésù Kírísítì, olódodo nìkan.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 2

Wo 1 Jòhánù 2:1 ni o tọ