Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 9:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó fa Júdà le bí mo ṣe fa ọrun mi le,mo sì fi Éfúráímù kún un,Èmi yóò gbé àwọn ọmọ rẹ ọkùnrin dìde, ìwọ Ṣíónì,sí àwọn ọmọ rẹ̀ ọkùnrin, ìwọ Gíríkì,mo ṣe ọ́ bí idà alágbára.

Ka pipe ipin Sekaráyà 9

Wo Sekaráyà 9:13 ni o tọ