Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 9:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọ̀rọ̀ Olúwa kọjú ìjà sí Hádírákì,Dámásíkù ni yóò sì jẹ́ ibi ìṣinmi rẹ̀;nítorí ojú Olúwa ń bẹ lára ènìyàn,àti lára gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì.

2. Àti Hámátì pẹ̀lú yóò ṣe ààlà rẹ̀Tírè àti Sídónì bí o tilẹ̀ ṣe ọlọgbọ́n gidigidi.

3. Tírè sì mọ odi líle fún ara rẹ̀,ó sì kó fàdákà jọ bí èkuru,àti wúrà dáradára bí àfọ̀ ẹ̀rẹ̀ ìgboro.

Ka pipe ipin Sekaráyà 9