Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 6:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni yóò sì kọ́ tẹ́ḿpìlì Olúwa òun ni yóò sì wọ̀ ní ògo, yóò sì jókòó, yóò sì jọba lorí ìtẹ́ rẹ̀; òun ó sì jẹ́ àlùfáà lorí ìtẹ́ rẹ̀; ìmọ̀ àlàáfíà yóò sì wá láàrin àwọn méjèèje.’

Ka pipe ipin Sekaráyà 6

Wo Sekaráyà 6:13 ni o tọ