Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 4:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ta ni ìwọ, ìwọ òkè ńlá? Ìwọ yóò di pẹ̀tẹ́lẹ̀ níwájú Serubábélì: òun yóò sì fi ariwo mú òkúta téńté orí rẹ̀ wá, yóò máa kígbe wí pé, ‘Ọlọ́run bùkún-un Ọlọ́run bùkún-un!’ ”

Ka pipe ipin Sekaráyà 4

Wo Sekaráyà 4:7 ni o tọ