Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 3:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí kíyèsí i, òkúta tí mo tí gbé kalẹ̀ níwájú Jóṣúà; lórí òkúta kán ni ojú méje wà: kíyèsí i, èmi yóò fín àkọlé rẹ̀,’ ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí, ‘èmi yóò sì mú ẹ̀bi ilẹ̀ náà kúrò ní ọjọ́ kan.

Ka pipe ipin Sekaráyà 3

Wo Sekaráyà 3:9 ni o tọ