Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 3:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Báyìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: ‘Bí ìwọ ọ́ bá rìn ní ọ̀nà mi, bí ìwọ yóò bá sì pa àṣẹ mi mọ́, ìwọ yóò sì ṣe ìdájọ́ ilé mi pẹ̀lú, ìwọ yóò sì ṣe àkóso ààfin mi, èmi yóò fún ọ ní àyè láti rìn láàrin àwọn tí ó dúró yìí.

Ka pipe ipin Sekaráyà 3

Wo Sekaráyà 3:7 ni o tọ